Yoruba Proverbs with Bidemi Ologunde
Podcast image
AI and the Yoruba Language
34 mins; December 13, 2025
Yoruba Cosmology and the UFO Question
23 mins; November 08, 2025
76. Olójúkan kì í tàkìtì òró.
23 mins; November 11, 2023
75. What Jagun Jagun Says About Power, Honor, and Yoruba Memory
24 mins; October 28, 2023
74. Can AI Preserve Òwe, or Only Copy It?
26 mins; October 14, 2023
73. Ojú kì í pón babaláwo kó bèèrè ebo àná.
24 mins; September 30, 2023
72. Oju baba ara; awon bi oju; asoro da bi agba
17 mins; September 16, 2023
71. Ohun ti ko to okoo ki i je agba niya
12 mins; September 02, 2023
70. Ofin ni yo so ara e; iyawo ti nna omo iyale
13 mins; August 19, 2023
69. O ye eni gbogbo ko so pe isu o jina, ko ye alubata
14 mins; August 05, 2023
68. "O ru ládugbó ò nrerá; kí ni ká so féni tó ru Òrìsà-a Yemoja?"
13 mins; July 29, 2023
67. "Ó bó lówó iyò, ó dòbu."
23 mins; July 15, 2023
66. "Níbo lo forúko sí tí ò njé Làmbòròkí?"
10 mins; July 01, 2023
65. "“Mo mò-ó gún, mo mò-ó tè,” niyán ewùrà-á fi nlémo."
15 mins; June 17, 2023
64. "Mélòó l’èjìgbò tí òkan è njé Ayé-gbogbo?"
14 mins; June 03, 2023
63. "Lásán kó là n dé etù; ó ní eni tórí è mbá etù mu."
16 mins; May 20, 2023
62. "Kò-sí-nílé kì í jagun enu tì."
15 mins; May 06, 2023
61. "Kò sí mi lájo àjo ò kún: ara è ló tàn je."
15 mins; April 29, 2023
60. "Kí ni ó ya àpón lórí tó fisu síná tó nsúfèé pé “bí a ti nse ni inú mbí won?”"
13 mins; April 15, 2023
59. "Kíni ànfàní-i kètèkètè lára kétékété à-gùn-fesè-wólè?"
9 mins; April 01, 2023
58. "Kàkà kí kìnìún se akápò ekùn, olóde a mú ode è se."
12 mins; March 18, 2023
57. "Ká ríni lóde ò dàbí-i ká báni délé."
16 mins; March 04, 2023
56. "Ibi tí a fi iyò sí ló nsomi sí."
10 mins; February 18, 2023
55. "ìrùkèrè kì í yan ifá lódì; oge, dúró o kí mi."
20 mins; February 04, 2023
54. "Ìpàkó onípàkó là nrí; enieléni ní nrí teni."
14 mins; January 21, 2023
53. "Ilé-ni-mo-wà kì í jèbi ejó."
14 mins; January 07, 2023
52. "Igúnnugún bà lé òrùlé; ojú tó ilé ó tó oko."
16 mins; December 28, 2022
51. "Ibi tí a ti npìtàn ká tó jogún, ká mò pé ogún ibè ò kanni."
15 mins; December 21, 2022
50. "Gbogbo òrò ní nsojú èké."
12 mins; December 14, 2022
49: "Gbogbo egbé nje Má-yè-lóyè, ò nje Sáré-pegbé."
15 mins; December 07, 2022
48. "Eye tó fi ara wé igún, èhìn àdìrò ní nsùn."
20 mins; November 30, 2022
47: "Eran kí la ò je rí? Òpóló báni lábàtà ó ba búrúbúrú."
14 mins; November 23, 2022
46: "Eni tí a ò fé nílùú kì í jó lójú agbo."
15 mins; November 16, 2022
45: "Eni tí a gbé gun elédè, ìwòn ni kó yò mo; eni tó gesin, ilè ló mbò."
17 mins; November 09, 2022
44: "Ení dádé ti kúrò lómodé."
18 mins; November 02, 2022
43: "Egbé eni là ngúnyán ewùrà dè."
23 mins; October 26, 2022
42: "Èèyàn bí òbo lòbo nya láso."
13 mins; October 19, 2022
41: "Èsúrú se fújà ó té lówó oníyán..."
22 mins; October 12, 2022
40: "Eégún wolé, ó ní òun ò rí Ejonto; Ejontó ní, “Àkísà ni, àbí kíní wolé?""
16 mins; October 05, 2022
39: "Dìgbòlugi-dìgbòlùùyàn, kò jé ká mo ajá tòótó."
32 mins; September 28, 2022
38: "Bí ojó ewúré ba pé, a ní kò sí ohun tí alápatàá lè fi òun se."
18 mins; September 21, 2022
37: "Bí olóde ò kú, òdee rè kì í hu gbégi."
19 mins; September 14, 2022
36: "Bí ojú bá rí, enu a dáké."
15 mins; September 07, 2022
35: "Bí kò sí tòbùn èèyàn, ta ni ìbá jí lówùúrò tí kó bójú sásá?"
16 mins; August 31, 2022
34: "Bí elébo ò bá peni, àsefín ò yeni."
17 mins; August 24, 2022
33: "Bí a kò bá tó baba omoó se, a kì í pe alákàrà."
19 mins; August 17, 2022
32: "Bí a kò bá tíì jókòó, a kì í nasè."
13 mins; August 10, 2022
31: "Bí a bá ti lè se là nwí; a kì í yan àna eni lódì."
10 mins; August 03, 2022
30: "Bí a bá mbá omodé jeun lóko, gànmùganmu imú eni ní nwò."
15 mins; July 27, 2022
29: "Ayò àyòjù làkèré fi nsé nítan."
13 mins; July 20, 2022
28: "Àáyá yó níjó kan, ó ní ká ká òun léhín òkánkán."
15 mins; July 13, 2022
27: "Aso àfòfún ò jé ká mo olówó."
13 mins; July 06, 2022
26: "Aròlèkè ò ro bàtà; gbédó gbédó ò ro ojúgun."
10 mins; June 29, 2022
25: "Apá èkúté-ilé ò ká awùsá; kìkìi yíyíkiri ló mo."
12 mins; June 21, 2022
24: "Àmòtékùn-ún fara jo ekùn, kò lè se bí ekùn."
14 mins; June 15, 2022
23: "Alásejù ní ngbébo kojá ìdí èsù; a-gbé-sàráà-kojá-mósálásí."
21 mins; June 08, 2022
22: "Àkùko adìye fi dídáji sàgbà; ó fi sísu-sílè sèwe."
19 mins; June 01, 2022
21: "Àjepò ni tàdán."
18 mins; May 25, 2022
20: Proverbs with a Special Guest - Wuraola Trebble (Nee Ogunsanya).
19 mins; May 18, 2022
19: Proverbs with a Special Guest - Olayinka Ejirinde.
19 mins; May 11, 2022
18: Proverbs with a Special Guest - Faramade Ogunlesi.
17 mins; May 04, 2022
17: Proverbs with a Special Guest - Oluwatobi Oladeji.
16 mins; April 27, 2022
16: Proverbs with a Special Guest - Yewande Aiyerin.
10 mins; April 20, 2022
15: Proverbs with a Special Guest - Olayinka Abisoye.
10 mins; April 13, 2022
14: "Àgbà kì í sorò bí èwe."
11 mins; April 06, 2022
13: "Àgbà kán se béè l’Ógùn; Yemoja ló gbé e lo."
10 mins; March 30, 2022
12: Proverbs with a Special Guest - Jeremiah Ifeoluwa Oyewole.
17 mins; March 23, 2022
11: "Adétèé sòrò méjì, ó fìkan puró; ó ní nígbàtí òún lu omo òun lábàrá, òún já a léèékánná pàtì."
7 mins; March 16, 2022
10: "Abánijeun bí aláìmora, ó bu òkèlè bí ègbón ìyá rè."
11 mins; March 09, 2022
9: "A pè ó lómo erín-màgbon, ò nyò; shé ìwo lo mi àgbon?"
8 mins; March 02, 2022
8: "A n sòrò olè, aláboyún ndáhùn; odiidi èèyàn ló gbé pamó."
9 mins; February 23, 2022
7: "A ngé e lówó, ó mbo òrùka."
10 mins; February 16, 2022
6: "A kì í yàgò fún “Mo gun esin rí.”"
6 mins; February 09, 2022
5: "A kì í mú oko lónà ká sèmélé; tajá teran ní mbúni."
6 mins; February 02, 2022
4: "A kì í kórira òfón-òn ka finá bo ahéré."
5 mins; January 26, 2022
3: "A kì í fi orí wé oríi Mokúsiré; bí Mokúsiré bá kú láàárò, a jí lálé."
7 mins; January 19, 2022
2: "A kì í dàgbà má láyà; ibi ayé bá báni là n je é."
7 mins; January 12, 2022
1: "A kì í bá oba pàlà kí okó oba má sánni lésè."
10 mins; January 05, 2022
Introduction (Start Here)
12 mins; December 22, 2021